ewole foba ologo julo - CAC HYMN

Edit Back to List

Tonic Solfa Notation

D D D R M F M R D R E wole f'Oba, Ologo, julo, R R R M F M R D T D E korin ipa ati ife Re; S L S S F M F M R D R Alabo wa ni at' Eni igbani, R R R M F F M R D T D O ngbe 'nu ogo, Eleru ni iyin

Lyrics

1. E wole f'Oba, Ologo, julo, E korin ipa ati ife Re; Alabo wa ni at' Eni igbani, O ngbe 'nu ogo, Eleru ni iyin 2. E so t'ipa Re, e so t'ore Re; 'Mole l'aso Re, gobi Re orun, Ara ti nsan ni keke 'binu Re je, Ipa ona Re ni a ko si le mo 3. Aye yi pelu ekun 'yanu Re Olorun! agbara Re l'o da won, O fi idi re mule, ko si le yi; O si f'okun se aso igunwa Re 4. Enu ha le so ti itoju Re? Ninu afefe ninu imole; Itoju Re wa nin' odo ti o nsan O si wa ninu iri ati ojo 5. Awa erupe aw'alailera 'Wo l'a gbekele, O ki o da ni Anu Re rorun o si le de opin Eleda, Alabo, Olugbala wa 6. 'Wo Alagbara Onife julo B'awon angeli ti nyin O loke Be l'awa eda Re, niwon t'a le se A o ma juba Re, a o ma yin O AMIN

Hymn Details

Hymn Number: 76
Created: Oct 4, 2025
Last Updated: Oct 4, 2025

Quick Actions

Edit Hymn

Print View

Perfect for keeping a physical copy while playing!