Okan mi yin Oluwa logo (oniruru; various hymn)
Tonic Solfa Notation
S S D S D S D R M
Okan mi yin Oluwa logo,
M F S R M F M R D
Oba iyanu t'O wa mi ri
S S D S D S D R M R D
Uno l'agogo iyin y'aye ka
M F S R M F M R D (MRDN)
Uno si fife Atobiju han
CHORUS
M M R D R D L S
Oluwa, ope ni fun O
M M R R D R D L S
Fun ore-ofe t'O fi yan mi
S S D S D S D R M R D
Jowo dimi mu titi dopin
M F S F M F M R D
Ki nle joba pelu Re loke
Lyrics
1. Okan mi yin Oluwa logo,
Oba iyanu t'O wa mi ri:
Uno l'agogo iyin y'aye ka
Uno si fife Atobiju han
Oluwa, ope ni fun O
Fun ore-ofe t'O fi yan mi,
Jowo dimi mu titi dopin
Ki nle joba pelu Re loke
2. Bi eranko l'emi ba segbe
Bikose ti Oyigiyigi;
Lairotele l'Emi Mimo de
T'O f'ede titun si mi l'enu
3. Ayo okan mi ko se rohin
Loro, losan, loganjo oru;
Gbat' Emi Mimo ti de 'nu mi
Mo nkorin orun lojojumo
4. Jesu ti la mi loju emi,
Mo si f'eti gbohun ijinle
O nse faji ninu okan mi;
Kini mba fi fun Olugbala?
5. Em'o sogo ninu Oluwa
K'emi ma ba di alaimore;
B'O ti pe mi iyanu l'o je
Awon angel d'olulufe mi
6. Mo damure lati sin Jesu
Lai f'ota pe larin aye yi;
Nibikibi t'O ba nto mi si
O daju ko ni jeki ndamu
7. Bi mba pari 're-ije l'aye,
Olugbala, ma je ki npofo;
Ni wakati na jeki ngbo pe,
Bo sinu ayo ayeraye
Amin
Hymn Details
| Hymn Number: | V003 |
| Created: | Oct 18, 2025 |
| Last Updated: | Oct 18, 2025 |
Quick Actions
Print View
Perfect for keeping a physical copy while playing!
Hymn Number: V003