Jesu nigba 'danwo

Edit Back to List

Tonic Solfa Notation

M M R D M D Jesu nigba 'danwo D R D L S Gbadura fun mi; D D D M S S K'emi ma ba se O F F M R M Ki nsi sako lo, M M R D M D 'Gba mba s'iyemeji D R D L S Ko b'oju wo mi, D D D M S S K'eru tab' isaju R F M R D Ma mu mi subu. CHORUS S S S L L L T D T L S M M M F F F S L S F M F S D D M S M D R F M R D

Lyrics

1. Jesu nigba 'danwo Gbadura fun mi; K'emi ma ba se O Ki nsi sako lo, 'Gba mba s'iyemeji Ko b'oju wo mi, K'eru tab' isaju Ma mu mi subu. 2. B'aye ba si nfa mi Pelu adun re, T'ohun 'sura aye Fe han mi l'emo, Jo mu Getsemani Wa s'iranti mi, Tabi irora Re L'oke Kalfari. 3. B'O ba pon mi l'oju Ninu ife Re. Da ibukun Re le Ori ebo na; Ki nf' ara mi fun O L'ori pepe Re: B'ara ko ago na, lgbagbo y'o mu. 4. 'Gba mo ba nre 'boji Sinu ekuru; T'ogo orun si nko L'eti bebe na; Un o gbekel' oto Re Ni 'jakadi 'ku Oluwa gb'emi mi, S'iye ailopin Amin

Hymn Details

Hymn Number: 839
Created: Oct 25, 2025
Last Updated: Oct 25, 2025

Quick Actions

Edit Hymn

Print View

Perfect for keeping a physical copy while playing!