Fi iyin fun Jesu, Olurapada wa

Edit Back to List

Tonic Solfa Notation

M S D M R M R D T L S D M S D M M R D R M R M S D M R M D T L S D M S F M R D T D M R D CHORUS R M R D S M M R M F M R M S D M M R D R M R M S D R M D T L S D M S F M R D T D M R D

Lyrics

1. Fi iyin fun Jesu, Olurapada wa, Ki aye k' okiki ife Re nla, Fi iyin fun! Eyin Angeli ologo, F'ola at'ogo fun oruko Re B'Olus'agutan, Jesu y'o to Omo Re, L'apa Re l'o ngbe won le l'ojojo; Eyin eniyan mimo ti ngb'oke Sion; Fi iyin fun pelu orin ayo 2. Fi iyin fun, Jesu Olurapda wa, Fun wa, O t'eje Re sile, O ku, On ni apata, ati reti 'gbala wa, Yin Jesu ti a kan m'agbalebu; Olugbala t'O f'ara da irora nla, Ti a fi ade egun de l'ori, Eniti a pa nitori awa eda Oba ogo njoba titi laelae 3. Fi iyin fun, Jesu Olurapada wa Ki ariwo iyin gba orun kan, Jesu Oluwa njoba lae ati laelae, Se l'Oba gbogb' eyin alagbara; A segun iku; fi ayo royin na ka, Isegun re ha da, isa oku? Jesu ye ko tun si wahala fun wa mo 'Tori O l'agbara lati gbala AMIN

Hymn Details

Hymn Number: 66
Created: Nov 9, 2025
Last Updated: Nov 9, 2025

Quick Actions

Edit Hymn

Print View

Perfect for keeping a physical copy while playing!