Ojo nla l‘ojo ti mo yan
Tonic Solfa Notation
s,: d. r: m:- s,: d: r: m:-
m: f: m: r:-d: m.: r: d:-
s,: d. r: m:- s,: d: r m:-
m: f: m: r:-d: m.: r d:-
O HAPPY DAY THAT FIXED MY CHOICE: Refrain
m. f: s:-d. r: m:-
m: f m: r:- d: m: r d:-
s: s.: s: s:- s: l.: s: m:-
s: s.: s s:- s: l. s: m:-
m. f: s:-d. r: m:-
m: f m: r:- d: m: r d:-
Lyrics
Ojo nla l‘ojo ti mo yan
Olugbala l‘Olorun mi;
O ye ki okan mi ma yo,
K‘o si ro ihin na kale
Ojo nla l‘ojo na
Ti Jesu we ese mi nu;
O ko mi ki nma gbadura
Ki nma sora, ki nsi ma yo,
Ojo nla l‘ojo na
Ti Jesu we ese mi nu.
2. Ise igbala pari na,
Mo di t‘Oluwa mi loni;
On l‘o pe mi, ti mo si je,
Mo f‘ayo j‘ipe mimo na.
3. Eje mimo yi ni mo je
F‘eni to ye lati feran:
Je k‘orin didun kun ‘le RE
Nigba mo ba nlo sin nibe
4. Simi, aiduro okan mi,
Simi le Jesu Oluwa;
Tani je wipe aye dun,
Ju odo awon angeli?
5. ‘Wo orun t o ngbo eje mi,
Y‘o ma tun gbo lojojumo,
Tit‘ ojo t‘emi mi y‘o pin
Ni uno ma m‘eje mi na se
Amin.
Hymn Details
| Hymn Number: | 869 |
| Created: | Nov 9, 2025 |
| Last Updated: | Nov 9, 2025 |
Quick Actions
Print View
Perfect for keeping a physical copy while playing!
Hymn Number: 869