Wa, eyin Olope wa

Edit Back to List

Tonic Solfa Notation

M F S M D R M Wa, eyin Olope wa M F S M D R M Gbe orin ikore ga M M F F R R M Ire gbogbo ti wole M F S D T L S K'otutu oye to de D D R D D R M Olorun Eleda wa M F S M M S L L'o ti pese f'aini wa L L S R S F M Wa k'a rele Olorun M L S D R M R D Gbe orin ikore ga

Lyrics

1. Wa, eyin Olope wa, Gbe orin ikore ga, Ire gbogbo ti wole K'otutu oye to de; Olorun Eleda wa, L'o ti pese f'aini wa; Wa k'a rele Olorun Gbe orin ikore ga. 2. Oko Olorun l'a je Lati s'eso iyin Re Alikama at'epo, Ndagba f'aro tab' ayo Ehu yo, ipe tele Siri oka si kehin; Oluwa 'kore mu wa Je eso rere fun O. 3. N'tori Olorun wa mbo Y'o si kore Re sile; On o gbon gbogbo panti Kuro l'oko re da nu; Y'o f'ase f'awon angel' Lati gba epo s'ina; Lati ko Alikama Si aba Re titi lae. 4. Beni, maa bo, Oluwa Si ikore, ikeyin Ko awon eeyan Re jo Kuro l'ese at'aro; So won di mimo laelae Ki won le ma ba O gbe Wa t' Iwo t'angeli Re Gbe orin ikore ga. Amin.

Hymn Details

Hymn Number: 655
Created: Nov 16, 2025
Last Updated: Nov 16, 2025

Quick Actions

Edit Hymn

Print View

Perfect for keeping a physical copy while playing!