Ojo nla l'ojo ti mo yan

Edit Back to List

Tonic Solfa Notation

S D M S D D R M M F M R D M R D S D M S D D R M M F M R D M R D CHORUS S S S S S L S M S S S S S L S M R M F M F S M F M R D M R D

Lyrics

1. Ojo nla l'ojo ti mo yan Olugbala l'Olorun mi; O ye ki okan mi ma yo, K'o si ro ihin na kale Ojo nla l'ojo na Ti Jesu we ese mi nu; O ko mi ki nma gbadura Ki nma sora, ki nsi ma yo, Ojo nla l'ojo na Ti Jesu we ese mi nu. 2. Ise igbala pari na, Mo di t'Oluwa mi loni; On l'o pe mi, ti mo si je, Mo f'ayo j'ipe mimo na. 3. Eje mimo yi ni mo je F'eni to ye lati feran: Je k'orin didun kun 'le RE Nigba mo ba nlo sin nibe 4. Simi, aiduro okan mi, Simi le Jesu Oluwa; Tani je wipe aye dun, Ju odo awon angeli? 5. 'Wo orun t o ngbo eje mi, Y'o ma tun gbo lojojumo, Tit' ojo t'emi mi y'o pin Ni uno ma m'eje mi na se Amin.

Hymn Details

Hymn Number: 869
Created: Nov 30, 2025
Last Updated: Nov 30, 2025

Quick Actions

Edit Hymn

Print View

Perfect for keeping a physical copy while playing!