Gbogbo aye gbe jesu ga (Raggae)

Edit Back to List

Tonic Solfa Notation

M M M M R M F F R D T S S F M M M M M R M F F R D T M M R D CHORUS S S S S M S L L R D T S F M R D M M M M R M F F R D T M M R D

Lyrics

1. Gbogbo aye, gbe Jesu ga, Angel', e wole fun; E mu ade Oba Re wa, Se l'Oba awon Oba 2. E se l'Oba eyin Martyr, Ti npe ni pepe Re; Gbe gbongbo igi Jese ga Se l'Oba awon oba 3. Eyin iru omo Israel', Ti a ti rapada; E ki Eni t'o gba yin la, Se l'Oba awon oba. 4. Gbogbo eniyan elese Ranti 'banuje yin; E te 'kogun yin s'ese Re, Se l'Oba awon oba 5. Ki gbogbo orile ede, Ni gbogbo agbaye, Ki won ki, ”kabiyesile” Se l'Oba awon oba 6. A ba le pel' awon t'orun Lati ma juba Re; K'a bale jo jumo korin, Se l'Oba awon oba AMIN

Hymn Details

Hymn Number: 77
Created: Dec 7, 2025
Last Updated: Dec 7, 2025

Quick Actions

Edit Hymn

Print View

Perfect for keeping a physical copy while playing!