Afi'yin ai'lopin

Edit Back to List

Tonic Solfa Notation

D R D S L S D D R M R D D M S M D R R M D R T D S D D D S L L L D R R R M D D D S L L L D R T D

Lyrics

1. A f'iyin ailopin Fun Olorun Baba, Fun ore aye wa At' ireti t'orun, O ran Qmo Re ayanfe Lati ku fun ese aye. 2. A fiyin ailopin Fun Olorun Omo T'o f'eje Re ra wa, Kuro ninu egbe, Nisiyi, O wa, O njoba O nri eso irora Re 3. A f'iyin ailopin Fun Qlorun Emi, Eni f'agbara Re So elese d'aye; O pari ise igbala O si fayo Orun k'okan. 4. A f'ola ailopin Fun Olodumare, 'Wo Ologo meta Sugbon okan soso, B'O ti ju imo wa lo ni, A o ma f'igbagbo yin O, Amin

Hymn Details

Hymn Number: 87
Created: Dec 7, 2025
Last Updated: Dec 7, 2025

Quick Actions

Edit Hymn

Print View

Perfect for keeping a physical copy while playing!