W a s'odo Jesu, mase duro

Edit Back to List

Tonic Solfa Notation

S, L, S, M, S, D R D L D D D R M D T L S S, L, S, M, S, D R D L D D D R M D CHORUS M M F M R R R L R R R M R D D T L S S, L, S, M, S, D R D L D D D R M D

Lyrics

1. W a s'odo Jesu, mase duro; L'oro Re l'o ti fona han wa, O duro li arin wa loni, O nwi pele pe, wa! Ipade wa yio je ayo, Gb'okan wa ba bo L'owo ese. T'a o si wa pelu Re, Jesu, N'ile ayeraye! 2. Jek'omode wa! E gb'ohun Re; Jek'okan gbogbo kun fun ayo, K'a si yan Jesu l'ayanfe wa, Ema duro, e wa. 3. Ranti p'O wa pelu wa loni, F'eti s'ofin Re, k'o si pamo; Gbo b'ohun Re ti nwi pele pe Eyin omo Mi wa. . Amin.

Hymn Details

Hymn Number: 214
Created: Dec 7, 2025
Last Updated: Dec 7, 2025

Quick Actions

Edit Hymn

Print View

Perfect for keeping a physical copy while playing!