ko suwa lati mako orin ti igbaani

Edit Back to List

Tonic Solfa Notation

D R M M M F S M R D L L S Ko su wa lati ma ko orin igbani D D D D S M D R M R Ogo f'Olorun Aleluya! D R M M M F S M R D L L S A le fi igbagbo korin na s'oke kikan D D D D S M D R D Ogo f'Olorun, Aleluya Chorus M F S S S S S S S L L L L S Omo Olorun ni eto lati bu s'ayo S S D D T L S Pe ona yi nye wa si S S L S F M R Okan wa ns'aferi Re S F M F M R D M S L L L L S Nigb'o se a o de afin Oba wa Ologo D D D D S M D R D Ogo f'Olorun, Aleluya!

Lyrics

1. Ko su wa lati ma ko orin igbani Ogo f'Olorun Aleluya! A le fi igbagbo korin na s'oke kikan. Ogo f'Olorun, Aleluya Omo Olorun ni eto lati bu s'ayo Pe ona yi nye wa si, Okan wa ns'aferi Re; Nigb'o se a o de afin Oba wa Ologo Ogo f'Olorun, Aleluya! 2. Awa mbe n'nu ibu ife t'o ra wa pada, Ogo f'Olorun Aleluya! Awa y'o fi iye goke lo s'oke orun; Ogo f'Olorun, Aleluya! 3. Awa nlo si afin kan ti a fi wura ko, Ogo f'Olorun Aleluya! Nibiti ao ri Oba Ogo n'nu ewa Re, Ogo f'Olorun, Aleluya! 4. Nibe ao korin titun t'anu t'O da wa nde, Ogo f'Olorun Aleluya! Nibe awon ayanfe yo korin 'yin ti Krist; Ogo f'Olorun, Aleluya! AMIN

Hymn Details

Hymn Number: 41
Created: Oct 4, 2025
Last Updated: Oct 5, 2025

Quick Actions

Edit Hymn

Print View

Perfect for keeping a physical copy while playing!