W a s'odo Jesu, mase duro
Tonic Solfa Notation
D R D L D F S F R
W a s'odo Jesu, mase duro
M M M S L F M R D
L'oro Re l'o ti fona han wa
D R D L D F S F R
O duro li arin wa loni
M M F S L F
O nwi pele pe, wa
Chorus
L L T L S S S R S
Ipade wa yio je ayo
S S L S F F M R D
Gb'okan wa ba bo L'owo ese
D R D L D F S F R
T'a o si wa pelu Re Jesu
M M F S L F
N'ile ayeraye!
Lyrics
1. W a s'odo Jesu, mase duro;
L'oro Re l'o ti fona han wa,
O duro li arin wa loni,
O nwi pele pe, wa!
Ipade wa yio je ayo,
Gb'okan wa ba bo L'owo ese.
T'a o si wa pelu Re,
Jesu, N'ile ayeraye!
2. Jek'omode wa! E gb'ohun Re;
Jek'okan gbogbo kun fun ayo,
K'a si yan Jesu l'ayanfe wa,
Ema duro, e wa.
3. Ranti p'O wa pelu wa loni,
F'eti s'ofin Re, k'o si pamo;
Gbo b'ohun Re ti nwi pele pe
Eyin omo Mi wa. .
Amin.
Hymn Details
| Hymn Number: | 214 |
| Key Signature: | G |
| Created: | Oct 4, 2025 |
| Last Updated: | Oct 4, 2025 |
Quick Actions
Print View
Perfect for keeping a physical copy while playing!
Hymn Number: 214