Okan mi yin Oba orun
Tonic Solfa Notation
S S L S S M S
Okan mi yin Oba orun
D D M S M D M R
Mu ore wa sode Re
S S L S M D M L
'Wo ta wosan, t'a dariji
D D M S M R R D
Tal' aba ha yin bi Re?
S S L S S M S
Yin Oluwa, Yin Oluwa
D D M S M D M R
Yin Oba Ainipekun
S S L S M D M L
Yin Oluwa, Yin Oluwa
D D M S M R R D
Yin Oba Ainipekun
Lyrics
1. Okan mi yin Oba orun,
Mu ore wa sode Re,
'Wo ta wosan, t'a dariji
Tal' aba ha yin bi Re?
Yin Oluwa, Yin Oluwa
Yin Oba Ainipekun
2. Yin fun anu t'o fi han
F'awon Baba 'nu ponju;
Yin I Okan na ni titi
O lora lati binu
Yin Oluwa, Yin Oluwa,
Ologo n'nu otito
3. Bi Baba ni O ntoju wa
O si mo ailera wa;
Jeje l'o ngbe wa lapa Re
O gba wa lowo ota,
Yin Oluwa, Yin Oluwa
Hymn Details
| Hymn Number: | 79 |
| Created: | Oct 11, 2025 |
| Last Updated: | Oct 11, 2025 |
Quick Actions
Print View
Perfect for keeping a physical copy while playing!
Hymn Number: 79