Gbogbo aye gbe jesu ga
Tonic Solfa Notation
S, D R M D R F M
M L T D L S
R M D F M L, R T
S D M F R D
Lyrics
1. Gbogbo aye, gbe Jesu ga,
Angel', e wole fun;
E mu ade Oba Re wa,
Se l'Oba awon Oba
2. E se l'Oba eyin Martyr,
Ti npe ni pepe Re;
Gbe gbongbo igi Jese ga
Se l'Oba awon oba
3. Eyin iru omo Israel',
Ti a ti rapada;
E ki Eni t'o gba yin la,
Se l'Oba awon oba.
4. Gbogbo eniyan elese
Ranti 'banuje yin;
E te 'kogun yin s'ese Re,
Se l'Oba awon oba
5. Ki gbogbo orile ede,
Ni gbogbo agbaye,
Ki won ki, ”kabiyesile”
Se l'Oba awon oba
6. A ba le pel' awon t'orun
Lati ma juba Re;
K'a bale jo jumo korin,
Se l'Oba awon oba
Hymn Details
| Hymn Number: | 77 |
| Created: | Dec 7, 2025 |
| Last Updated: | Dec 7, 2025 |
Quick Actions
Print View
Perfect for keeping a physical copy while playing!
Hymn Number: 77