Hymn Solfa Manager
All Hymns
Add Hymn
Edit Hymn: Gbogbo aye gbe jesu ga
Title
*
Hymn Number
Key Signature
Select Key
C
G
D
A
E
B
F#
F
Bb
Eb
Ab
Db
Gb
Time Signature
Select Time
4/4
3/4
2/4
6/8
2/2
3/8
Tempo (BPM)
Category
Mark as Favorite
Solfa Notation
*
S, D R M D R F M M L T D L S R M D F M L, R T S D M F R D
Tips:
Use Do, Re, Mi, Fa, Sol, La, Ti for major scale. Use lowercase for minor scale (do, re, mi, fa, sol, la, ti).
Lyrics
1. Gbogbo aye, gbe Jesu ga, Angel', e wole fun; E mu ade Oba Re wa, Se l'Oba awon Oba 2. E se l'Oba eyin Martyr, Ti npe ni pepe Re; Gbe gbongbo igi Jese ga Se l'Oba awon oba 3. Eyin iru omo Israel', Ti a ti rapada; E ki Eni t'o gba yin la, Se l'Oba awon oba. 4. Gbogbo eniyan elese Ranti 'banuje yin; E te 'kogun yin s'ese Re, Se l'Oba awon oba 5. Ki gbogbo orile ede, Ni gbogbo agbaye, Ki won ki, ”kabiyesile” Se l'Oba awon oba 6. A ba le pel' awon t'orun Lati ma juba Re; K'a bale jo jumo korin, Se l'Oba awon oba
Notes
View Hymn
Back to List
Update Hymn